Smiley face

DjAbass: Akinkanju onise amuludu ilu Ọba Biritiko

Abass Tijani (DjAbass)
Gbogbo wa la mọ wi pe ọgbọn ju agbara lọ. Sugbon awon Yooba lo ni laakaye ni baba ọgbọn. Bi eniyan ba wa lọgbọn to ni laakaye ti ko ba ni akinkanju, iru wọn ki i rèré ọja jẹ.

Pẹlu asayan ọrọ yii ni maa fi ma se afihan ogbontarigi, akikanju onisẹ alariya ati agbatẹru amuludun to pegede julọ niluu Ọba Biritiko, Abass Tijani, eni ti ọpọlọpọ mọ gẹgẹ bi DjAbass.

Odu ni Abass Tijani, ki i se aimo foloko. Mo pinnu lati se afihan okunrin naa lonii gege bi ojulowo omo Yoruba ti n soju ile Naijiria daada loke okun.
 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment