Smiley face

Ike Ekweremadu wa ninu ẹgbẹ imulẹ awon agba?

Ohun to ba wu onikaluku lo le so lenu, niwon igba ti ofin Naijiria ti faaye sile fun onikaluku lati se esin tabi darapo mọ egbe to ba wu u. 

Sugbon sa, igba akoko ni yii ti igbakeji olori ile igbimo asofin agba, Ike Ekweremadu, yoo se awon nnkan to mu ifura dani pelu ona ikinni rẹ pelu awon eniyan kan pato. 

Awon eniyan kan ni oseese ki maanu naa je okan lara awon omo egbe imule to lagbara pupo.

Kini ero yin nipa eleyii.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment