Smiley face

Taani akinkanju eniyan?

Taani akinkanju?

Akinkanju ni eniyan ti ko je ki ipenija tabi isoro ti n la koja di i lowo lati le tesiwaju ninu erogba tabi ala to ni fun igbe aye re.

Adura mi ni wi pe, gbogbo igbiyanju,ilakaka wa ko ni ja sori ofo laye. Amin.


@OlayemiOniroyin

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment