Smiley face

Olufimo ati Arabanbi ti n ta si ara won lori ọrọ Seun Egbẹgbẹ

O dabi ẹni wi pe awon ẹbi Olufimo ti bẹrẹ si ni tasi awon ẹbi Arabanbi wi pe, awon ni ololufẹ Seun Ẹgbẹgbẹ ti won lo ji foonu loja Computer Village. Oro yii ni Ogbeni Ahmed Olanrewaju Lawal naa fesi pada si nigba to n se afihan bi Seun Egbegbe se n naa Saheed Osupa, to je Olufimo1, lowo loju agbo.
"GBOGBO EYIN OLUFIMO TI EN SO ISOKUSO WIPE FANS ARABANBI NI SEUN EGBGBE NITORI OHUN TIO SELE EJOWO TANI OWA LOJU PHOTO YII AAAHHH OWO EPO NI EYIN OLUFIMO OOOO." -Ahmed Olanrewaju Lawal

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment