Smiley face

Orisun TV: Oriire ti de fun awon oloja, onise ọwọ ati olokoowo

https://my.notjustok.com/track/download/id/154246
Ọpọlọpọ awon eniyan lo ro wi pe eniyan gbọdọ lowo rẹpẹtẹ ko to le polowo ọja lori Telifsan nla bi Orisun TV. 

Nigba ti awon kan gba wi pe ọja tabi isẹ ti eniyan gbe dani gbọdọ jẹ erin nla ko to le di ohun ti won le polowo lori telifisan. 

Enu yoo ya yin ti mo ba so fun yin nipa owo tasẹrẹ to le mu yin se ipolowo oja tabi isẹ yin lori telifisan Orisun.
 


O ya, ẹ jẹ ka sọrọ fun ẹkurẹrẹ alaye:

Phone: +2348073617207

Whatsapp: +2348032394964

Email: yemoford@gmail.com

Download Promo
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment