Smiley face

Alvin Alphons [@realalvinmusic] ti de pelu orin-emi to gbamuse

ALVIN ALPHONS
Kosi ibi ti eniyan ti le wu ko ti wa, to ba ti jẹ wi pe lotito ni a fi ran-an, dandan ni ki ti ẹ jọju. Olorin emi ni ALVIN ALPHONS, agbekale orin rẹ si fi ye wa wi pe lotito ni a fi ise orin ran an. Mi o ni so pupo nipa rẹ, sugbon mo fi dayin loju wi pe ẹ o gba pelu mi ti ẹ ba gbọ awon orin rẹ to gbe jade.

HE WILL DO Download 
I SALUTE      Download

ONLY YOU    Download
IKE (POWER) Download

E le kan is Alvin Alphons lori awon oju opo yii 
Twitter: @realalvinmusic
Facebook: Realalvinmusic
Phone number: +234810219668
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment