Smiley face

Fashion On The Street: Bayii ni ẹ se le di oloriire lọdun 2017

West African Fashion Week
Eniyan ti yoo di oloriire ni lati gbe igbesẹ akin ko le debi ti ayọ rẹ wa. Ẹni ba jade si gbangba laye n ri, awon si ni won gbe larugẹ.



Akanse eto kan ti bẹrẹ bayii eleyii ti won pe ni ST. EVE WEST AFRICAN FASHION WEEK lati sọ ọpọ awọn eniyan di oloriire ojiji lodun 2017.



Ti ẹyin ba jẹ sabẹrẹ-dowo-di -tailor (fashion designer) mo ki yin ku oriire.



Ti ẹ ba jẹ aserun lọsọ (stylist) mo ba yin yọ sẹsẹ.



Eyin asojuloge (make-up artist), onise-oge (model), tabi ayaworan (photographer), odun 2017 ni okiki yin yoo kan kari aye pelu eto yii

Bawo ni ẹ se le jẹ anfaani yii?


Ki n to tẹsiwaju ninu alaye mi, ma royin ki ẹ  dara pọ mọ wa loju òpó wa lori ayelujara fun awon alaye lekunrẹrẹ.


Facebook: African Fashion Week
 
Twitter: @SEWAFW123


Lati kopa ninu idije yii,  ẹgbẹrun marun-un pere owó  naira (#5,000) ni ẹ fi ra fọọmu nipa sisan owo naa sinu apo ifowopamọ to wa nisalẹ yii.

UBA BANK
A/C Name: St Eve Concepts LTD
A/C No: 100676573815


Leyin eyi ni ẹ fi oruko yin, fọto pelebe, ati isori ise ti ẹ  n se ninu awon ise ti a la kalẹ soke yii. Ẹ wa fi won sọwọ si: event@eveconcepts.com 
#Lobatan

Asiko rẹ ni yii, ma je ko fo ọ da. Gbe igbese ni kiakia.  Eto yii wa fun lati gbe awon eniyan dide soke ati lati so awon eniyan kekere di ni nla. Ọwọ rẹ lo ku si bayii, Olayemi Oniroyin ti gbiyanju to fun ọ.
Ẹ tun le pe sori nọmba yii 07035830239.

#Ire o
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment