Smiley face

Kunle Afolayan ati iya re rode ariya

Add caption
Kosi ohun todun bi k'obi wa laye ma jẹun ọmọ nigba ti ọmọ n se aseyọri to si n goke agba. Adura mi ni wi pe, ki gbogbo awon obi jẹun omo won, ki awon omo naa si di oloriire niseju awon obi won. Kunle ati iya rẹ ni yii lode ariyan. Ẹ ẹ ri wi pe okẹjẹgbẹ...
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment