Smiley face

Adeniyi Johnson ti bọ sinu agbami ifẹ tuntun?

Ọpọlọpọ awon eniyan ni won ti bẹrẹ si ni gbe e kiri bayii wi pe ọrọ ifẹ ti n da Adeniyi Johnson ati Seyi Edun, ti awon mejeeji je osere, papo bayii.
Seyi Edun
Bi o tile je wi pe iroyin naa ko ti fidi mulẹ, sugbon ohun ti agbọ ni wi pe iwole-wode ti n waye laaarin awon mejeeji. Eyikeyi ninu awon tọrọ kan naa ni ko ti jeri si iroyin naa boya bẹẹ gẹlẹ lo ri.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments:

  1. Sugar Mummy is Real!!!
    Do you need Sugar Mummy/Daddy? Hurry up now and contact Mrs Sandra on (08140553826) she just linked/hooked me up with a rich sugar mummy after I have been played/scamed online by some other people all the name of sugar mummy, no much talks hurry up now call her (Mrs. Sandra) on (+2348140553826) and testify/see for your own self don’t waist time, she is genuine, just follow her rules and in 24hours she will link you up! Allah she is nice.

    ReplyDelete