Smiley face

Buhari wa nibi ayeye ibura fun aare tuntun ilu Ghana lonii

Won ti bura fun aare tuntun Akufo-Addo lonii [7th Jan 2017]ni orileede Ghana. Aare Muhammadu Buhari wa lara awon alejo pataki nibi ayeye naa to waye ni gbagede  Black Star Square




Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment