Smiley face

E wa wo angeli Ireti omo ti aye fẹ pa danu

Aimoye eniyan mimọ lo jẹ oniwa rirun. Bẹẹ si ni, aimoye awon eniyan ti aye n pe ni ẹlẹsẹ ni won yoo ri oju rere Olorun gba nikẹyin aye. Sebi orun nikan lo mọ ẹni ti o la. Eniyan wo ara, sugbon Olorun wo ọkan. Enikeni ti iwo ba nipa lati se iranlowo fun oun naa ni enikeji rẹ, toju rẹ.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment