Smiley face

Ayeye ojo ibi: Yemi Solade le odun kan lonii

Yemo Solade
Oni ni ojo ibi agba-ọjẹ onise sinima, Yemi Solade. Aimoye awon eniyan kaakiri agbaye ni won si ti n bayo fun ojo ayo to ko naa. Awa naa fi asiko naa ki i ku odun tuntun. Ire owo, ayo, alaafia ati emi gigun. Ase. 

Happy Birthday
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment