Smiley face

Event Radio FM ti gori afẹfẹ

 


Ohun to daju ni wi pe ti eniyan ba n duro dọjọ ti n nnkan yo rọrun ko to da nnkan se yoo pẹ. O si seese ki nnkan naa ma waye nitori ko si igba kan taa ya sọtọ lati gbe ohun kan se, eniyan ni yoo pinnu lati dide ko si gbiyanju ohun to ba fẹ se.



Kini akawe mi dale lori, mo fẹ kede rẹ fun yin wi pe mo ti se idasilẹ redio ayelujara,  Event Radio FM.



Maa ma salaye siwaju si i nipa rẹdio naa laipẹ.



E seun gidigidi gan-an fun aduroti yin.



Olayemi Olatilewa

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment