Smiley face

Leyin Odun mẹrinla, ohun t'ORI se fun Muyiwa Ademola ni yii


Awon Yoruba bọ, won ni ori ti o gbeni ni i gbe alawoore koni. Kadara si wa ninu akunleyan. Ayafi ẹni ba n binu ori ni o sọ wi pe Muyiwa Ademola ko pegede ninu kagbe itan sinima to loorin kale.

Ggẹ bi Saheed Akorede omo Okunola se so ninu orin rẹ kan, O ni awon orin oun se e fi we wura pẹlu fadaka, ati wi pe, bi won se n dowó lonii ni won tun dọla rẹpẹtẹ bo dọla.
Ohun ti Osupa k lorin yii ni a le fi se apejuwe ohun to sẹlẹ si Muyiwa Ademola pẹlu fiimu rẹ to se ni nnkan bi odun merinla (14yrs) sẹyin eleyii to tun un pada pere fun-un. 

Ilu Amerika ni ọkọ Omolara wa bayii pelu ẹbi rẹ. Ibẹ naa ni enikan ti gbe fi ọkọ̀ tuntun talọrẹ latari akitiyan rẹ ninu sinima ORI to se ni nnkan bi odun mẹrinla sẹyin.
 Àlàyé ti Authentic se ni yii nisalẹ
"ORI" a 14 year old film that keep bringing me fortune👏. He is Apostle Tope Onileowo. He said he watched "ORI" for the first time about 4 months ago, he wept, started asking about me and God said he should give me some amount(in dollars💲😉), he started taking the money around with him coz I was still in Naija then. We met when I got here and he gave me the money. Now he said God directed him to bless me with this car. Indeed God knows our inner thoughts😎. Please join me in thanking him and praying for his ministry Rock of Prayer Christian Centre in Houston TX. Much love sir.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment