Smiley face

Photographer wo ni yoo jẹ ẹbun owo #0.5M ninu odun tuntun?

Photographer wo ni yoo jẹ ẹbun 500, 000 ninu odun tuntun?
Boya ẹyin ko ti gbọ, anfaani ti si silẹ fun gbogbo awọn ayaworan bayii lati di olokiki nla. Bakan naa ni won yoo ni anfaani lati jẹbun owó #500, 000 ninu ètò akanse ST. EVE WEST AFRICAN FASHION WEEK.

Anfaani to wa nibẹ?

  • Idanilẹkọ nipa foto yiya ode-oni pẹlu awon irinsẹ igbalode
  • Afihan awon isẹ́ yin ninu magasiini Vogue agbaye
  • Ọgbọn iriri lati ọdọ awon ayaworan ti won ti goke agba
  • Ipolowo isẹ yin
  • Àgbàse isẹ oke okun
  • Idije lati jẹ #500, 000
 Bawo ni ẹ se le jẹ anfaani yii?


Fun alaye lekunrẹrẹ, ma royin ki ẹ  dara pọ mọ wa lori:

www.westafricanfashionweek.style

ati 

Facebook: African Fashion Week

Twitter: @SEWAFW123  

Lati kopa ninu idije yii,  ẹgbẹrun marun-un pere owó  naira (#5,000) ni ẹ fi ra fọọmu nipa sisan owo naa sinu apo ifowopamọ to wa nisalẹ yii.

UBA BANK
A/C Name: St Eve Concepts LTD
A/C No: 100676573815

Leyin eyi ni ẹ fi oruko yin, fọto pelebe, ati ise ti ẹ  n se sọwọ si: event@eveconcepts.com. E tun le pe nọmba yii fun alaye: 07035830239


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment