Smiley face

Jide Kosoko ti pada senu ise leyin iku Henrietta Kosoko

Bi eniyan ba fi ogun odun sedaro eni to ku, eni to ku ko le pada wa sile aye mo. Ododo oro ni!

Olorun nikan lo si mo ohun ti ko ye enikeni. Jide Kosoko ti pada senu ise re leyin iku iyawo re, Henrietta Kosoko.

Aimoye awon eniyan ni won so isokuso kaakiri nipa Omooba Kosoko leyin iyawo eleeketa to ku nile re.

Sugbon sa, bi o tile je wi pe ibanuje nla ni isele naa dale sile, a dupe wi pe Jide Kosoko ti n gbe e kuro lokan diedie.

Adura wa ni wi pe, ki Oluwa duro ti idile re ati awon omo re pata.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment