Smiley face

A n wa iwe eri Dino Melaye - Ile igbimo asofin agba

Image result for dino melaye 
Awon omo ile igbimo asofin agba  tile Naijiria ti bere si ni se iwadii latari esun ti won fi kan Senato Dino Malaye to wa lati ipinle Kogi. Gege bi iroyin ti ile ise iroyin Sahara gbe jade, won fesun kan maanu naa wi pe ko ni iwe eri ati wi pe, ko kawe jade ni Ifafiti ABU to wa ni Zaria. 

Alaye ti okan ninu awon osise ileewa naa so ni wi pe, awon ko ri akosile kankan to so nipa iwe eri senato naa. 

Sugbon sa, Melaye so wi pe, iro patapata ni gbogbo aheso oro naa. Koda, Senato Malaye so wi pe, oun ti bere si ni kawe gboye eleekeji ninu ogba leewe naa. Lobatan

Ju gbogbo re lo, ile igbimo asofin ti gbe igbimo kan dide lati se iwadii lori ibi ti sabuke melaye wole si to be je wi pe lotito lo ni sabuke.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment