Smiley face

Oyun merin fun ore merin leekan naa


Awamaridi ni Olorun oba, gbogbo ise re lo dara. Awon ore merin loyun po nigba kan naa. Ohun to dara ni. Edumare ba wa pese fun awon ti n woju re fun omo rere









Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment