Smiley face

Aare Muhammed Buhari lo n pa awon ara ilu" — PDP lo so bee

Image result for apc and pdp
Egbe PDP ti fesun kan ijoba Muhammadu Buhari ati egbe APC gege bi eni ti n sokunfa bi awon eniyan se n gba emi ara won lojiji. Won ni ilu le, nnkan ko fararo, ara si n ni awon ara ilu jojo. Alaye yii ni won se loju opo ero twitter won @OfficialPDP,
Ohun ti won wi ni yii: “Nigerians should hold APC Nigeria and Muhammadu Buhari government responsible for the rampant suicide and suicide attempts”.

“The failure of APC Nigeria led government to provide basic amenities and revive our ailing economy has forced Nigerians to commit suicide

"APC Nigeria professionally corrupt and visionless government is reason for suicide and many killings in Nigeria”.
Ti e ko ba gbagbe, nnkan bi ojo meloo kan seyin ni Dokita Allwell Orji ko sinu omi lati ori afara Third Mainland leyin re la tun ri awon obirin meji kan ti won ni aye ti su awon latari gbese ti n be lorun won. Awon naa gbiyanju lati be somi, sugbon ori ko won yo.

Se Buhari lo fa eleyii lotito?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment