Smiley face

Ninu awon ilu to lewu lati se abewo si lagbaye, Amerika fi Naija si ipo karun-una(5th)

Image result for nigeria and america 
Ile ise ijoba ile Amerika ti gbe atejade kan sita lati si awon omo ilu won leti nipa aabo emi won lagbaye. 

Eleyii ti won se nigba ti won gbe atejade awon ilu to lewu ti won le se abewo si lagbaye jade. Ipo Karun-un ni won fi Naijiria, ilu olominira, ilu to san fun wara ati oyin, ilu alaafia ati awon eniyan olopolo pipe. 

Ilu to wa ni ipo kinni ni Mexico 
Ipo keji ni Mali, 
ipo keta ni Isreal ati Pakistan, 
ipo kerin ni Iraq, 
nigba ti Afghanistan, Nigeria, Syria wa ni ipo karun-un.

Awon omo Naija ti bere si ni tutu soke bayii ti won si n foju gba lori ayelujara. Won ni o dabi eni mi wi pe, Ogbeni Trump ko mo bo se n lo. Ati wi pe, o kan wu won lati fi rederede re ilu Naija lara ni.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment