Smiley face

Aye ara mi ni mo n je: Ini Edo gbeyo pelu aso oge tuntun


Bi o tile je wi pe Ini Edo naa ti wa lara awon oserebirin ti igbeyawo won ti tuka, sugbon eyi ko fi ibi kankan pana idunnu re. Inu ile ara re lo n gbe, aye ara re lo n je.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment