Smiley face

Aya 2baba ta lenu bi robo alata

 
Kaakiri aye ni awon eniyan ti n se apeere Annie aya agba olorin, 2baba, gege bi omobirin to mo bi won sen  jere okan okunrin. Aimoye isele lo ti sele leyin igba ti 2baba pada Annie, aimoye obirin ni won ba a du ololufe re, sugbon nikeyin nko? Igba funfun lo pade rile omi. Annie lo pada joba loode Innocent. Laipe yii ni won se ayeye odun merin ti won fera won nisuloka. O si ti to nnkan bi odun mejidinlogun, 18yrs, ti awon mejeeji ti pade gege bi ololufe.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment