Smiley face

Idan amani:Kayeefi sele nipinle Imo

Se emi gan an ko ni bere irinkerindo Olayemi Oniroyin bayii pelu awon nnkan ti mo ri lenu ojo meta yii. A fi ki Oluwa saanu fun mi o. Ariwa ipinle Imo leyii ti sele. O fe jobi eni wi pe maanu naa n pidan ni. Bawo ni eniyan yoo se ti ida bo ara re nikun ti yoo si tun gara chicken kaakiri igbo? Idan lo lorita!


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment