Smiley face

Ayinde Barrister ko lo mu "FUJI" wa sile aye- K1 de Ultimate


Nibi apero kan to waye ni King Wasiu Ayinde Marshal ti gbe salaye ero okan re nipa Fuji. Sugbon alaye re dabi eni wi pe ko ba ibi to dun leti awon olugbo re. 

Oba Fuji asiko yii tun pada wa sori ayelujara lati salaye ohun to ni lokan gan-an. Ninu alaye re, Olu Omo of Lagos, salaye wi pe, lotito ati lododo Ayinda Barrister lo yi orin were pada si fuji. Sugbon orisii oro ti n je "fuji" ti wa tele ninu oro ojoojumo ni awon igba kan seyin. 

Ni akoko naa, o ni awon eniyan won maa kira won wi pe, "kini Fuji e?".
Sugbon opolopo awon eniyan ni won ta koo wi pe iro ni, won ni Sikiru Ayinde lo mu Fuji waye ati wi pe oruko naa ko si ninu ede saaju ki Alhaji Agba to seda oruko naa.

Awon kan an yin K1 fun agbekale ogbon to safihan nigba ti awon kan ri gege afojudi si Sikiru Ayinde Barrister to je ipile Fuji.



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment