Smiley face

Nje igbaaya obirin si wa lara ibi ikoko ara?

 
Nje a si le gba wi pe igbaaya obirin si wa lara ibi ikoko pelu bi awon obirin se n si aya won sile laye ode oni? 

Obirin ti ko ba ti si igbaaya sile ko ti soge.

O ni lati je wi pe won ti yo igbaaya kuro lara ibi ikoko ara. Pelu bi nnkan se n lo bayii, afaimo ki awon ibi ikoko mii ma di ohun ti won yoo ma se afihan re lojutaye. Kini ero yin nipa awon isele yii?

 
 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment