Smiley face

Bidemi Kosoko ti gba oko lowo mi - Oserebirin onitia pariwo fun gbogbo aye

 
Bi a se n pana okan ni imii tun ru jade. Awon oserebirin meji, Bidemi Kosoko & Bose Alao Omotoyossi ni won ti n ja si okunrin ti oruko re n je Omotoyosi Razack, eni to je agbaboolu.

Bose la gbo wi pe, oun ni ololufe Razack tele sugbon ti Bidemi to je omo Jide Kosoko n yo omokunrin naa fe bayii.

Ore Bose kan lo tu asiri naa fun un. Gbogbo bi itakuroso si se waye laarin Bose ati ore re to tu asiri naa fun un lo fi sori ayelujara nibi to ti n beere fun imoran awon ololufe re lori isele naa







Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment