Smiley face

Won ti ri oku okunrin to ko sinu omi lEko Ambode

 
Okunrin dokita ti won pe oruko re ni Allwell Orji, eleyii to be sinu omi lati ori afara 3rd mainland to wa niluu Eko, ni won ti ri oku re fayo bayiii ninu omi. Awon agbofinro ti kan si ebi okunrin naa lati wa gbe oku re.

Allwell Orji lo be sinu omi ni ojo Aiku, March 20, to koja yii. titi di akoko yii, enikeni ko le so idi ti okunrin naa fi gba emi ara re.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment