Smiley face

Ina ti n jo lori ayelujara pelu foto omoge Davido nigba kan ri

2017-03-21%2B10.39.39.png
Okan ninu awon ololufe atijo Dafidi omo Adeleke ti gbogbo eniyan mo si Davido, Sira Kante, lo ti be si ni kos gosilo lori ayeluja bayii pelu awon foto re tuntun. 

Onise oge ni Sira Kante, ife to wa laarin oun ati Davido, omo baba olowo, wa sopin nigba ti omoge naa gbo nipa omo ti ibatan Dele Momodu, Sophia Momodu bi fun. Sebi e mo wi pe orisa je n pe meji obirin ko denu.

Sira Kante dudu, dudu re ko jana. Bee lo dan gbirin bi ide. Awe itan re le lowo bi edo ti won ko jade ninu omi. Awon foto omo naa to ya leti okun ti bere si ni pariwo soke bayii lori ayelujara.

Eyin naa e ye wo ke.
2017-03-21%2B10.39.21.png 
2017-03-21%2B10.39.05.png 
2017-03-21%2B10.39.39.png
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment