Smiley face

El-Rufai ti konfaamu e: Ti e ba ni mo tako Buhari, bee naa lori

 El Rufai and Buhari [Photo: Pulse.ng]
Gomina ipinle Kaduna, Malam El-Rufai ti konfaamu re wi pe, lotito ati lododo, oun loun ko leta to lu sita naa si Buhari. Ati wi pe ohun to ba wu eniboodi ni ko ma fenu so nigboro aye.

Leta kan ti n fo kiri ayelujara nikopekope yii ni won lo towo baba kukuru ilu Kaduna jade, eleyii ti won lo ko si Aare Buhari nikoko.

Ninu leta naa ni El Rufai ti se kilokilo fun Buhari wi pe nnkan ko wa "palatebu" fun awon omo Naija ati wi pe, awon ti won yii Buhari ka, oju aye ni won se, won ko le eepu.

Sugbon sa, ninu oro gomina ipinle Kaduna, o ni oun mo wi pe awon kan ti won ko nife Buhari ninu igbimo re lo tu leta naa sita. 

"Igba akoko ko ni yii ti ma ko leta si Buhari. Mi o si ko leta na lati bi ijoba re wo, sugbon lati mu jigiri si awon nnkan to se pataki. Bakan naa, mi o kabamo pe leta naa lu sita. Sebi eniyan ki i teyin ka ko tun maa dowo boo. Ti enikeni ba si ro wi pe mo ko leta naa lati fi tako o ni, bee naa ni", - El Rufai lo so bee.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment