Smiley face

Ibere Orin Apala, Fuji ati itan igbe aye Bobby Benson to se idasile Highlife nile Nigeria 1

Image result for ayinla omowura
Iwadii ti a se fi ye wa wi pe, orisii orin kan ti wa saaju ti n je Olalomi eleyii ti ko si ipa re mo laye ode oni. 

Awon kan ni, ni igba ti apala yoju ni orin naa poora; nigba ti awon kan se alaye wi pe, orisii orin ti n je Olalomi naa lo yira pada si apala.
Bakan naa ni won salaye Osho Oba, eleyii to je bi Oga si Ayinla Omowura gege bi olorin to ko orisii orin Olalomi yii ko to wa di apala.
Siwaju sii, orisii orin ti n je ajisari ko fe e yato si orisii orin ti n je were.
Akoko ti won se amulo won ni yoo so oruko ti won yoo pe orin naa. Sugbon agbekale kan naa ni awon orin mejeeji ni.

Ajisari je eyi ti won ko ni akoko awe musulumi lati fi ji saari, nigba ti were je eleyii ti won ko lasiko faaji. Sugbon okan naa ni orin yii, ko si iyato kankan nibe rara. 

Were lo di Fuji, Lai ni fi oro si abe ahon so, kosi ibi ti won ko ti gba lagbaye wi pe Bausati Sikiru Ayinde Agbajelola ni ipile orin Fuji. Eyi ni wi pe, owo Sikiru ni were ti yi pada di Fuji eleyii to ti wa di gbajugbaja bayii.

Ju gbogbo re, ti a ba n so nipa orin Highrlife nile Nigeria. Benard Olabinjo Benson ti gbogbo eniyan mo si Bobby Benson ni ibere tabi ipile orin naa. 

Taani Bobby Benson?

E tesiwaju NIBI
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment