Smiley face

Iya Stephanie Otobo ti lo fenu gbole niwaju Apostle Sulaiman Johnson

 
Iya omobirin onise nabi, Stephanie Otobo, to ni ololufe ikoko oun ni Apostle Sulaiman Johnson, ni iya re ti lo tuuba bayii nile ijosin ojise Olorun naa. 


Iya omobirin naa toro idariji lowo Apostle Sulaiman latari iro bantabanta ti omo re pa. Ohun ti a si gbo ni wi pe, ojise Olorun ti dariji won patapata. 

Koda, egbon Stephanie tun tele iya won lati seri oro naa.
 
 
 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment