Smiley face

Okiki Olajumoke omo oniburedi ti dide niluu Jamani

 
Ti faili eniyan ba wa niwaju Oluwa lode orun, onitoun yoo ma gbe igbe aye re bi oba ni lode aye. 


Nigba ti awon eniyan ro wi pe ariwo Olajumoke Orisaguna ti n lole niluu Naijiria, okiki re tun ti bere si ni kan bayii niluu Jamani pelu foto olokiki re nibi to n gbe kiri buredi tun se gba irawo gege bi foto eleekefa ninu awon foto to laponja julo lagbaye.
 
Alaye omobirin naa ni yii:

"Aunty TY @tybello look what I found!!! My photo bomb picture was voted number 6 best picture in the world yesterday on a TV program called Galileo on Prosieben TV in Germany , while my story was told to inspire people.


Thanks to @berveleen.m for taking pictures/videos and sending to my inbox.
God bless you.
Grace found me!!!
Thanks to my management @qtabyevents for constant work.
#olajumoke #smallgirlbigGod #grace "
 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment