Smiley face

Lara Olubo loba asiko yii!

Oloju ologbon ti n fogbon tore.
Gbogbo eni mo loju ko leniire.
Aimoye ika eniyan ni sun ni soosi.

Sugbon tOmolara Omobolaji yato gedegede.
Gbogbo ogbon to gbon ni fi i somo araye loore.
Iwa tutu bi adaba lo fi daniyi kaye.

E wa waya Olubo bi ti n jaye bi oba Elisabeeti.
Ninu oge sise Mojisinuola ti jawe olubori.
Ka soro isipaya lo fi doosa akunlebo ninu ise enu.
Emi fori bale foba alade, Lara Olubo loba asiko yii.

Olojo-ibi oni, igba ile re ko ni fo
Awo ile re ko ni faya.
Eni gbe koto ofin de o fun ra re ni o jin si.
Iyaloja maa jaye lo ko si Pressure.


 #HappyBirthday

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment