Smiley face

Saraki ti ko sinu wahala tuntun N3.5bn: EFCC ti lo fejo sun Buhari ki won to bere ija

Senate President Bukola Saraki
Bukola Saraki

Ajo ti n gbogun ti iwa jegudujera, EFCC ti kowe si Aare Muhammed Buhari lori owo ti olori  ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, ati awon isomogbe re komi bi kolokolo. 


Won ni owo to n lo bi nnkan bi bilionu meta abo owo naira, N3.5bn, ti won dabaru yii lo je lara owo eya ti won rigba to je ti Paris Club. 

Ninu leta oloju mewaa ti ajo EFCC fi ranse, gbogbo awon arijenimadaru ti won ran Saraki lo ati gbogbo ete ti won lo lati fi iboju bo eka isejoba loju ni won salaye lekunrere.
 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment