Smiley face

Aisha Buhari ti soro nipa ilera oko re

 
Obirin akoko orileede Naijiria, Arabirin Aisha Buhari ti salaye wi pe, ipo ilera oko oun ti n se aare ile yii, Muhammadu Buhari, ko buru to bi awon eniyan se n gbe kiri.

Arabirin yii se alaye wi pe, ailera re ko ni ko ma se awon ojuse re gege bi aare ile yii. Bakan naa lo dupe lowo awon afenifere ati gbogbo omo Naijiria lapapo fun awon adura won ti won gba lojoojumo.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment