Smiley face

Awon omoge ti won fibadi pawo pade

Bi won ba n so nipa ibadi to gbajumo lawujo agbaye, ni o joniloju ti Kim Kardashian  ko ba jeyo nipo kinni, nitori apoti aje ti mbe leyin re, joojumo ni pawo wole bi bisineesi epo robi. 
 
Okan lara iru e tun ni osuka bambam ti mbe leyin Nicki Minaj. Awon oniroyin amuludun agbaye tile salaye wi pe, pupo ninu awon onworan orin Nicki Minaj maa wa sagbo re, ki i se nipa orin ti n ko, bi ko se lati wa wo ibadi re.

Laipe yii ni awon mejeeji pade, won jo, won si yo mo ra won.
"Olayemi Oniroyin, ki wa ni koko iroyin gan-angan?"
 
Ko si koko kankan, o kan wu mi ki n fi akoko yin sere lasan ni. To ba biyin ninu , ile ni mo wa,  o ya e wa na mi. Errk
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment