Smiley face

Awon fi oro iku sawada pelu Trump niluu Amerika

Gbogbo nnkan ni eniyan le fi sawada bi toro iku ko. Ati wi pe bo se wa ni Liki bee lo wa ni Gbanja.

Bi awon eniyan kan se n gbero iku si Buhari bee ni awon kan naa se ni Ilu Amerika pelu Trump.

Sugbon sa, se bo se ye ko ri ni yen? Awon Yoruba ni ta a ba n ja bi kaku ko.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment