Smiley face

Wizkid gbe tuntun jade pelu Chris Brown: African Bad Girl

Bi omo eni ba dara ka wi, ki i sebi ka fi saya. Ayo Ibrahim omo Balogun ni irawo re ti lo soke si i pelu bo se jumo korin pelu gbajugbaja onkorin ilu Amerika, Chris Brown.

Ninu Orin WizKid to pe ni "African Bad Girl" lo ti ledipo pelu Chris Brown fun adun orin tuntun eleyii si mu irawo re tan si i lawujo amuludu agbaye.

Eyin naa le gbo orin tuntun naa nibi: https://my.notjustok.com/track/download/id/223771

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment