Smiley face

Awon hausa se aponle Oonirinsa nipinle Jigawa

 
Eniyan to n wa owo lo to pade iyi lona, toba rowo sebi iyi naa ni yoo fi ra. Awon Hausa se aponle Ooni Ile Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi nipinle Jigawa nibi ayeye ifinijoye Alhaji Nasiru Haladu Danu gege bi Dan Amanar Dutse ni aafin Emir tiluu Dutse.

Won se alaye Ojaja gege bi oba ti ki i se alaso funfun nikan sugbon eni ti inu re funfun lai ni abawon. Nibi ayeye naa ni Misita fun igbokegbodo oko, Chibuike Rotimi Amaechi naa ti pade Ooni to si wi pe inu oun dun lati ri Adimula Ile Ife leekan si.
 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment