Smiley face

Awon omilegbe ero jade wa woju Efe ni Warri

  
Eniyan ti ko ni lonii leni to ba di tumoro (tomorrow) ko de tun maa gbadun lo bee laye lo, eni ti ko ni lonii ko maa banuje. Asanyan yii je ti Ayinla Omowura, ki Edua dele foba orin Apala. Nibi ka diju ka si laa, Efe to jawe olubori ninu ididje Big Brother Naija deni apewo nigba to se abewo si awon eniyan re ni Warri
 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment