Smiley face

E wa oko Rolls Royce ti won se niluu Naijiria

 
Aimoye olopolo ati onilaakaye eda ni Olorun fi ta ile Naijiria lore, kosi sohun to ni ki Naija ma wa ninu awon ilu to ti goke lagbaye.

Sugbon, o joni loju wi pe sibesibe, adiye wa ko ti niye lapa.
 
Okunrin atokose kan ti oruko re n je Muhammad Abdul Modibbo ti inagije re je Modibbo Automobile to wa nipinle Benue la gbo wi pe o pa kadara oko yerinbeto (Volkswagen Beetle) to si yipada si oko Rolls Royce, iru eyi ti Ooni Ojaja fi n jaye. Bi ko tile mu tan, sugbon o ye ka gbe oriyin fun un fun ise opolo to laponja to se.
 
 
Ti okunrin yii ba ri iranlowo to paye, odaju wi pe yoo pa opolopo idan ti yoo ya araye lenu.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment