Smiley face

Ayeye aadota odun (50) ti won da ipinle Eko sile yoo waye ni Jamani:Ayantunde Oyinbo setan lati filu dara

Ayantunde Oyinbo. 



 

Awon egbe agbasaga ile Yoruba ti won kale siluu Jamani, Yoruba Elite Club, ti setan lati se ayeye aadota odun (50) ti won da ipinle Eko sile bayii ni ilu Munich to wa ni Germany.
Ayantunde Oyinbo onilu ola

Ayeye ti yoo waye lojo kokandinlogun ati ogunjo osu karun un odun 2017 ni Sefiu Alao omo oko yoo ti ma pede ara pelu awon agba olorin to ku.

Lara awon ti won yoo ma da awon eniyan laraya ni Ayantunde Anselm Ramacher ti eniyan mo si Ayantunde Oyinbo.

Fun alaye lekunrere:

Lagos@50

Date: Friday, 19 May 2017

Time: 9am-6pm (Exhibition) & 6pm-11pm (Launching)

Venue: EineWeltHaus München, Schwanthalerstr. 80, 80336 Munich, Germany

+
Ankara Carnival

Date: Saturday, 20 May 2017

Time: 5 pm- 3am

Venue: DT Tanzschul-Holding, Adolf-Kolpingstr. 10, 80336 Munich, Germany
Contact to organiser:

+4915211898224

+4915211908325

+4915214836321

Email: info@yorubaeliteclub.com
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment