Smiley face

Dele Bravo: Ayeye ogun odun (20yrs) lori itage

Image may contain: 9 people, people smiling, text 
Ojo aboki ti pe ni Sabo. Dele Bravo ti kuro ninu ojewewe olorin ti won beere pe taani korin. Nibayii, agbaoje olorin yii ti setan lati se ayeye ogun odun ti aye ti gbadun 2raya pelu jufuji ti dun leti araye. Ojo keje osu karun un odun yii ni. 

O ya, e je ka pade nibe.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment