Smiley face

Igbeyawo mi lo tuka, idunnu mi si wa sibe - Oserebirin onitiata

 
Oserebirin onitiata, Tonto Dikeh, ti salaye wi pe, ayo ati idunnu oun si wa sibe, eleyii ti Olorun fi ta oun lore nipa omo alalubarika ti oun ni. 

Omobirin yii lo ko oko re, Olakunle Churchill, sile latari esun to fi kan oko re wi pe, gbogbo igba lo maa na oun bi aso ofi. 

Ati wi pe, o ni oko oun maa n se yodiyodi nigboro aye eleyii to fi karun wa sile fohun. Ninu alaye re, o ni aimoye igba ni oun fi toju arun ibalopo ti oko oun ko wale.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment