Smiley face

Mo le paayan nitori Wizkid - Bobrisky

Untitled.png 
Omokunrin to so ara di omobrin osan gangan, Bobrisky ti so wi pe oun le paayan nitori Wizkid. Igba akoko ko ni yii ti Bobrisky ti n fi ife han si Wizkid gege bi eni to wuu  lati je ololufe re. Sugbon ife gbigbona oteyi tun ga.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment