Smiley face

Kemi Olunloyo ti n toro owo lati bo ninu wahala to kosi

Gbajugbaja akoroyin ayelujara, Kemi Olunloyo ti n be awon ololufe re lati seto ikowojo fun un lati fi yanju ejo to wa niwaju re.

Gege bi awon ololufe re se so, won ni omo gomina ipinle Oyo nigba kan ri si wa logba ewon niluu Pota nibi to ti n je ewa olomi sooroso pelu ise asekara.

Ti e ko ba gbagbe, Ojise Olorun David Ibiyeomie lo fi olopaa gbe Kemi leyin ti omobirin naa ko iroyin jade wi pe, pasito naa ba awon omo ijo ire sun.

Ti eyin ba ni owo ti fe fi ran an lowo, e le fi owo naa si apamo banki yii:

First Bank of Nigeria
Name Olukemi Olunloyo
Sort Code FBNINGLA
Account number: 3020832750

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment