Smiley face

Iyawo Seun Egbegbe bimo tuntun

NikkyBerry, ololufe Seun Egbegbe bimobirin lonii. Sugbon sa, Egbegbe to je baba omo si wa latimole awon olopaa titi di akoko yii lori esun ole ati jibiti ti won fi kan an.

Ki Oluwa ba wa da omo naa si. Amin

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment