Smiley face

Oko Mercy Aigbe si wa latimole

Gbogbo igbiyanju agbejoro Ogbeni Lanre to je oko Mercy Aigbe lati gba Ogbeni Lanre jade lahamo lo jasi pabo. O ti n lo bi ojo bi meloo kan bayii ti oko Mercy Aigbe ti wa latimole leyin to na iyawo re bi ole ti won gbamu l'Ojuelegba. Nje igbese Mercy Aigbe yii dara tabi o ku die kaato nipa titi baba omo re mole?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment