Smiley face

Lionel Messi pe ogbon (30) odun laye

Igbe aye eda dabi tete baba ijebu ni. Bi eniyan ko ba ta ko le je. Bi eniyan ba tun ta, o le je, o si le ma je.

O wu Eleda lo pe ki Lionel Messi je lo.

Ojo kerinlelogun osu kefa odun 1987 ni won bi saye ni orileede Argentina. Enikeni ko si le so bi igbe aye re yoo se ri lojo ti won bi saye. Sugbon lonii, Oosa apebo lo je lawujo ere boolu agbaye.

Messi ni iwadii fiye wa wi pe owo to n gba losoose (weekly) je N140m pelu awon esunrere mi ti n wole fun un lojoojumo.

A ba Messi yo, igba odun, odun kan ni.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment