Smiley face

Ibadi Mercy Johnson ti da wahala ati Surutu kale bayii

Nibi gbagede orin faaji to waye ni Anambra eleyii ti Glo se agbateru re ni Mercy Johnson ti bere si fi ibadi jo bi okoto. Ijo ti a n so yii po debi wi pe, awon okunrin to wa nibe fe le ma tosi sokoto.

Ipada re ni bi awon eniyan se n bu iya olomo meta naa pelu bo se n judi sibi judi soun bi awon omo olosho.

"Ise mi ni mo n se, mo je okan lara awon adari ayeye naa, mi o si ri ohun to baadi ninu ki n fi ibadi jo. Ati wi pe, oko mi ko kompileeni. Ki wa ni ejo ti yin?" - Mercy Aigbe lo da won lohun pada bee.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment